Àgàbàgebè; Ẹ̀tàn 2Kọ 6:4, 6; Jem 3:17 Àpẹẹrẹ inú Bíbélì: Mt 23:7, 23-28—Jésù dẹ́bi fáwọn aṣáájú ẹ̀sìn torí pé ẹlẹ̀tàn ni wọ́n Ga 2:11-14—Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù bá àpọ́sítélì Pétérù wí torí pé ó jẹ́ alágàbàgebè