ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 45:17, 18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Fáráò wá sọ fún Jósẹ́fù pé: “Sọ fún àwọn arákùnrin rẹ pé, ‘Ohun tí ẹ máa ṣe nìyí: Ẹ di ẹrù lé àwọn ẹran tí ẹ fi ń kẹ́rù, kí ẹ lọ sí ilẹ̀ Kénáánì, 18 kí ẹ sì mú bàbá yín àti agbo ilé yín wá sọ́dọ̀ mi níbí. Màá fún yín ní àwọn ohun rere ilẹ̀ Íjíbítì, ẹ ó sì jẹ ohun tó dára jù* ní ilẹ̀ yìí.’+

  • Jẹ́nẹ́sísì 47:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Ísírẹ́lì wá ń gbé ní ilẹ̀ Íjíbítì, ní Góṣénì,+ wọ́n tẹ̀ dó síbẹ̀, wọ́n bímọ, wọ́n sì ń pọ̀ gan-an.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́