-
Sáàmù 105:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Ọlọ́run mú kí àwọn èèyàn rẹ̀ pọ̀ rẹpẹtẹ;+
Ó mú kí wọ́n lágbára ju àwọn ọ̀tá wọn lọ,+
-
Ìṣe 7:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 “Bó ṣe ku díẹ̀ kí ìlérí tí Ọlọ́run ṣe fún Ábúráhámù ṣẹ, àwọn èèyàn náà gbilẹ̀, wọ́n sì di púpọ̀ ní Íjíbítì,
-
-
-