ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 7:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Jèhófà wá sọ fún Nóà pé: “Wọ inú áàkì, ìwọ àti gbogbo ìdílé rẹ, torí ìwọ ni mo rí pé ó jẹ́ olódodo níwájú mi nínú ìran yìí.+

  • Ìsíkíẹ́lì 14:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 “‘Bí àwọn ọkùnrin mẹ́ta yìí bá tiẹ̀ wà níbẹ̀, Nóà,+ Dáníẹ́lì+ àti Jóòbù,+ ara wọn* nìkan ni wọ́n á lè gbà là torí òdodo+ wọn,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.”

  • Hébérù 11:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ìgbàgbọ́ mú kí Nóà  + fi ìbẹ̀rù Ọlọ́run hàn, lẹ́yìn tó gba ìkìlọ̀ láti ọ̀run nípa àwọn ohun tí a kò tíì rí,+ ó kan ọkọ̀ áàkì+ kí agbo ilé rẹ̀ lè rí ìgbàlà; ó dá ayé lẹ́bi nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ yìí,+ ó sì di ajogún òdodo irú èyí tí ìgbàgbọ́ ń mú wá.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́