-
Jẹ́nẹ́sísì 28:13, 14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Wò ó! Jèhófà wà lókè rẹ̀, ó sì sọ pé:
“Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run Ábúráhámù bàbá rẹ àti Ọlọ́run Ísákì.+ Ìwọ àti àtọmọdọ́mọ*+ rẹ ni màá fún ní ilẹ̀ tí o dùbúlẹ̀ sí yìí. 14 Ó dájú pé àtọmọdọ́mọ* rẹ yóò pọ̀ bí erùpẹ̀ ilẹ̀,+ ìwọ yóò sì tàn káàkiri dé ìwọ̀ oòrùn àti ìlà oòrùn, dé àríwá àti gúúsù, ó sì dájú pé gbogbo ìdílé ayé yóò rí ìbùkún gbà*+ nípasẹ̀ ìwọ àti àtọmọdọ́mọ* rẹ.
-