ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 2:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Béèrè lọ́wọ́ mi, màá fi àwọn orílẹ̀-èdè ṣe ogún fún ọ

      Màá sì fi gbogbo ìkángun ayé ṣe ohun ìní fún ọ.+

  • Àìsáyà 11:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ní ọjọ́ yẹn, gbòǹgbò Jésè+ máa dúró bí àmì* fún àwọn èèyàn.+

      Ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn orílẹ̀-èdè máa yíjú sí fún ìtọ́sọ́nà,*+

      Ibi ìsinmi rẹ̀ sì máa di ológo.

  • Mátíù 2:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 ‘Ìwọ Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ti ilẹ̀ Júdà, lọ́nàkọnà, ìwọ kọ́ ni ìlú tó rẹlẹ̀ jù lára àwọn gómìnà Júdà, torí inú rẹ ni alákòóso ti máa jáde wá, ẹni tó máa ṣe olùṣọ́ àgùntàn àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.’”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́