Jẹ́nẹ́sísì 25:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ọjọ́ ayé Íṣímáẹ́lì jẹ́ ọdún mẹ́tàdínlógóje (137). Ó mí èémí ìkẹyìn, ó sì kú, wọ́n kó o jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ̀.* 18 Wọ́n tẹ̀ dó sí Háfílà+ nítòsí Ṣúrì,+ tó sún mọ́ Íjíbítì, títí lọ dé Ásíríà. Wọ́n sì ń gbé nítòsí gbogbo àwọn arákùnrin+ wọn.*
17 Ọjọ́ ayé Íṣímáẹ́lì jẹ́ ọdún mẹ́tàdínlógóje (137). Ó mí èémí ìkẹyìn, ó sì kú, wọ́n kó o jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ̀.* 18 Wọ́n tẹ̀ dó sí Háfílà+ nítòsí Ṣúrì,+ tó sún mọ́ Íjíbítì, títí lọ dé Ásíríà. Wọ́n sì ń gbé nítòsí gbogbo àwọn arákùnrin+ wọn.*