Àìsáyà 45:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Mo dá ìmọ́lẹ̀,+ mo sì ṣe òkùnkùn,+Mo dá àlàáfíà,+ mo sì ṣe àjálù;+Èmi Jèhófà ni mò ń ṣe gbogbo nǹkan yìí. 2 Kọ́ríńtì 4:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí Ọlọ́run ni ẹni tó sọ pé: “Kí ìmọ́lẹ̀ tàn láti inú òkùnkùn,”+ ó sì ti tan ìmọ́lẹ̀ sí ọkàn wa+ láti mú kí ìmọ̀ ológo nípa Ọlọ́run mọ́lẹ̀ nípasẹ̀ ojú Kristi.
7 Mo dá ìmọ́lẹ̀,+ mo sì ṣe òkùnkùn,+Mo dá àlàáfíà,+ mo sì ṣe àjálù;+Èmi Jèhófà ni mò ń ṣe gbogbo nǹkan yìí.
6 Torí Ọlọ́run ni ẹni tó sọ pé: “Kí ìmọ́lẹ̀ tàn láti inú òkùnkùn,”+ ó sì ti tan ìmọ́lẹ̀ sí ọkàn wa+ láti mú kí ìmọ̀ ológo nípa Ọlọ́run mọ́lẹ̀ nípasẹ̀ ojú Kristi.