ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 22:16-18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 ó sọ pé: “‘Mo fi ara mi búra pé torí ohun tí o ṣe yìí,’ ni Jèhófà+ wí, ‘tí o kò kọ̀ láti fún mi ní ọmọ rẹ, ọ̀kan ṣoṣo+ tí o ní, 17 ó dájú pé màá bù kún ọ, ó sì dájú pé màá mú kí ọmọ* rẹ pọ̀ bí àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run àti iyanrìn etí òkun,+ ọmọ* rẹ yóò sì gba ẹnubodè* àwọn ọ̀tá+ rẹ̀ lọ́wọ́ wọn. 18 Gbogbo orílẹ̀-èdè tó wà láyé yóò gba ìbùkún fún ara wọn nípasẹ̀ ọmọ*+ rẹ torí pé o fetí sí ohùn+ mi.’”

  • Sáàmù 105:9-11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Májẹ̀mú tó bá Ábúráhámù dá+

      Àti ìbúra rẹ̀ fún Ísákì,+

      10 Èyí tó gbé kalẹ̀ bí ìlànà fún Jékọ́bù

      Àti bíi májẹ̀mú tó wà títí láé fún Ísírẹ́lì,

      11 Ó ní, “Màá fún ọ ní ilẹ̀ Kénáánì+

      Bí ogún tí a pín fún yín.”+

  • Hébérù 6:13, 14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Torí nígbà tí Ọlọ́run ṣe ìlérí fún Ábúráhámù, ó fi ara rẹ̀ búra, nígbà tó jẹ́ pé kò sí ẹlòmíì tó tóbi jù ú lọ tó lè fi búra,+ 14 ó sọ pé: “Ó dájú pé màá bù kún ọ, ó sì dájú pé màá mú kí o di púpọ̀.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́