Jẹ́nẹ́sísì 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Màá mú kí ìwọ+ àti obìnrin+ náà di ọ̀tá+ ara yín,* ọmọ* rẹ+ àti ọmọ* rẹ̀+ yóò sì di ọ̀tá. Òun yóò fọ́ orí rẹ,*+ ìwọ yóò sì ṣe é léṣe* ní gìgísẹ̀.”+ Róòmù 9:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe torí pé wọ́n jẹ́ ọmọ* Ábúráhámù+ ni gbogbo wọn fi jẹ́ ọmọ; kàkà bẹ́ẹ̀, “Látọ̀dọ̀ Ísákì ni ọmọ* rẹ yóò ti wá.”+ Gálátíà 3:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àwọn ìlérí náà la sọ fún Ábúráhámù àti fún ọmọ* rẹ̀.+ Kò sọ pé, “àti fún àwọn ọmọ* rẹ,” bíi pé wọ́n pọ̀. Kàkà bẹ́ẹ̀, ó sọ pé, “àti fún ọmọ* rẹ,” ìyẹn ẹnì kan ṣoṣo, tó jẹ́ Kristi.+
15 Màá mú kí ìwọ+ àti obìnrin+ náà di ọ̀tá+ ara yín,* ọmọ* rẹ+ àti ọmọ* rẹ̀+ yóò sì di ọ̀tá. Òun yóò fọ́ orí rẹ,*+ ìwọ yóò sì ṣe é léṣe* ní gìgísẹ̀.”+
7 Bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe torí pé wọ́n jẹ́ ọmọ* Ábúráhámù+ ni gbogbo wọn fi jẹ́ ọmọ; kàkà bẹ́ẹ̀, “Látọ̀dọ̀ Ísákì ni ọmọ* rẹ yóò ti wá.”+
16 Àwọn ìlérí náà la sọ fún Ábúráhámù àti fún ọmọ* rẹ̀.+ Kò sọ pé, “àti fún àwọn ọmọ* rẹ,” bíi pé wọ́n pọ̀. Kàkà bẹ́ẹ̀, ó sọ pé, “àti fún ọmọ* rẹ,” ìyẹn ẹnì kan ṣoṣo, tó jẹ́ Kristi.+