ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 17:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Májẹ̀mú tí mo bá ọ dá nìyí, òun sì ni ìwọ àti àtọmọdọ́mọ* rẹ yóò máa pa mọ́: Gbogbo ọkùnrin tó wà láàárín yín gbọ́dọ̀ dádọ̀dọ́.*+

  • Jẹ́nẹ́sísì 17:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Ábúráhámù wá mú Íṣímáẹ́lì ọmọ rẹ̀ àti gbogbo ọkùnrin tí wọ́n bí nínú ilé rẹ̀ àti gbogbo ẹni tó fi owó rà, gbogbo ọkùnrin inú agbo ilé Ábúráhámù, ó sì dá adọ̀dọ́ wọn* ní ọjọ́ yẹn gan-an, bí Ọlọ́run ṣe sọ fún un.+

  • Jẹ́nẹ́sísì 22:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Torí náà, Ábúráhámù jí ní àárọ̀ kùtù, ó de ohun tí wọ́n fi ń jókòó mọ́ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀,* ó sì mú méjì nínú àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ dání pẹ̀lú Ísákì ọmọ rẹ̀. Ó la igi tó fẹ́ fi dáná ẹbọ sísun náà, ó gbéra, ó sì lọ síbi tí Ọlọ́run tòótọ́ sọ fún un.

  • Jẹ́nẹ́sísì 22:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Ó sì sọ pé: “Má pa ọmọ náà, má sì ṣe ohunkóhun sí i, torí mo ti wá mọ̀ báyìí pé o bẹ̀rù Ọlọ́run, torí o ò kọ̀ láti fún mi+ ní ọmọ rẹ, ọ̀kan ṣoṣo tí o ní.”

  • Hébérù 11:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Ìgbàgbọ́ mú kí Ábúráhámù+ ṣègbọràn nígbà tí a pè é, ó lọ sí ibì kan tó máa gbà, tó sì máa jogún; ó jáde lọ, bí kò tiẹ̀ mọ ibi tó ń lọ.+

  • Jémíìsì 2:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Ṣebí a ka Ábúráhámù bàbá wa sí olódodo nípa àwọn iṣẹ́ lẹ́yìn tó mú Ísákì ọmọ rẹ̀ lọ sórí pẹpẹ?+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́