Jẹ́nẹ́sísì 36:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ísọ̀ fẹ́ ìyàwó láàárín àwọn ọmọ Kénáánì: Ádà+ ọmọ Élónì ọmọ Hétì;+ Oholibámà+ ọmọ Ánáhì, ọmọ ọmọ Síbéónì ọmọ Hífì; 3 àti Básémátì+ ọmọ Íṣímáẹ́lì, arábìnrin Nébáótì.+
2 Ísọ̀ fẹ́ ìyàwó láàárín àwọn ọmọ Kénáánì: Ádà+ ọmọ Élónì ọmọ Hétì;+ Oholibámà+ ọmọ Ánáhì, ọmọ ọmọ Síbéónì ọmọ Hífì; 3 àti Básémátì+ ọmọ Íṣímáẹ́lì, arábìnrin Nébáótì.+