29 Jékọ́bù fèsì pé: “O mọ bí mo ṣe sìn ọ́, o sì mọ bí mo ṣe tọ́jú agbo ẹran rẹ;+ 30 díẹ̀ lo ní kí n tó dé, àmọ́ agbo ẹran rẹ ti wá pọ̀ sí i, ó ti di púpọ̀ rẹpẹtẹ, Jèhófà sì ti bù kún ọ látìgbà tí mo ti dé. Ìgbà wo ni mo wá fẹ́ ṣe ohun tó máa jẹ́ ti agbo ilé mi?”+