-
Jẹ́nẹ́sísì 31:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Mo lágbára láti fìyà jẹ ọ́, àmọ́ Ọlọ́run bàbá rẹ bá mi sọ̀rọ̀ lóru àná pé, ‘Ṣọ́ ohun tí o máa sọ fún Jékọ́bù, ì báà jẹ́ rere tàbí búburú.’+
-