Jẹ́nẹ́sísì 31:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ọlọ́run bá Lábánì ará Arémíà+ sọ̀rọ̀ lójú àlá ní òru,+ ó sọ fún un pé: “Ṣọ́ ohun tí o máa sọ fún Jékọ́bù, ì báà jẹ́ rere tàbí búburú.”*+
24 Ọlọ́run bá Lábánì ará Arémíà+ sọ̀rọ̀ lójú àlá ní òru,+ ó sọ fún un pé: “Ṣọ́ ohun tí o máa sọ fún Jékọ́bù, ì báà jẹ́ rere tàbí búburú.”*+