Jẹ́nẹ́sísì 27:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Ṣùgbọ́n Ísọ̀ di Jékọ́bù sínú torí pé bàbá rẹ̀ ti súre fún un,+ Ísọ̀ sì ń sọ lọ́kàn ara rẹ̀ pé: “Ọjọ́ tí a máa ṣọ̀fọ̀ bàbá mi ti ń sún mọ́lé.+ Lẹ́yìn náà, ṣe ni màá pa Jékọ́bù àbúrò mi.” Jẹ́nẹ́sísì 32:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Mo bẹ̀ ọ́,+ gbà mí lọ́wọ́ Ísọ̀ ẹ̀gbọ́n mi, torí ẹ̀rù rẹ̀ ń bà mí, ó lè wá gbógun ja èmi+ àti àwọn ọmọ mi pẹ̀lú àwọn ìyá wọn.
41 Ṣùgbọ́n Ísọ̀ di Jékọ́bù sínú torí pé bàbá rẹ̀ ti súre fún un,+ Ísọ̀ sì ń sọ lọ́kàn ara rẹ̀ pé: “Ọjọ́ tí a máa ṣọ̀fọ̀ bàbá mi ti ń sún mọ́lé.+ Lẹ́yìn náà, ṣe ni màá pa Jékọ́bù àbúrò mi.”
11 Mo bẹ̀ ọ́,+ gbà mí lọ́wọ́ Ísọ̀ ẹ̀gbọ́n mi, torí ẹ̀rù rẹ̀ ń bà mí, ó lè wá gbógun ja èmi+ àti àwọn ọmọ mi pẹ̀lú àwọn ìyá wọn.