ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 25:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Ábúráhámù fẹ́ ìyàwó míì, Kétúrà ni orúkọ rẹ̀. 2 Nígbà tó yá, ó bí Símíránì, Jókíṣánì, Médánì, Mídíánì,+ Íṣíbákì àti Ṣúáhì.+

  • Ẹ́kísódù 2:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Lẹ́yìn náà, Fáráò gbọ́ ohun tó ṣẹlẹ̀, ó sì fẹ́ pa Mósè; àmọ́ Mósè sá lọ torí Fáráò, ó sì lọ ń gbé ní ilẹ̀ Mídíánì.+ Nígbà tó dé ibẹ̀, ó jókòó sẹ́gbẹ̀ẹ́ kànga kan.

  • Nọ́ńbà 31:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “Gbẹ̀san+ lára àwọn ọmọ Mídíánì+ torí ohun tí wọ́n ṣe fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Lẹ́yìn náà, a máa kó ọ jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ.”*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́