-
Jẹ́nẹ́sísì 20:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ọlọ́run tòótọ́ sọ fún un lójú àlá pé: “Mo mọ̀ pé òótọ́ inú lo fi ṣe ohun tí o ṣe, torí ẹ̀ ni mi ò fi jẹ́ kí o dẹ́ṣẹ̀ sí mi. Ìdí nìyẹn tí mi ò fi jẹ́ kí o fọwọ́ kàn án.
-
-
Sáàmù 51:àkọléBíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Sí olùdarí. Orin Dáfídì, nígbà tí
wòlíì Nátánì wọlé wá bá a lẹ́yìn tí Dáfídì bá Bátí-ṣébà lò pọ̀.+
-
-
Sáàmù 51:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Torí náà, olódodo ni ọ́ nígbà tí o bá ń sọ̀rọ̀,
Ìdájọ́ rẹ sì tọ́.+
-