ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 3:19, 20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Àmọ́ èmi fúnra mi mọ̀ dáadáa pé ọba Íjíbítì kò ní jẹ́ kí ẹ lọ àfi tí mo bá fi ọwọ́ agbára mú un.+ 20 Ṣe ni màá na ọwọ́ mi láti fìyà jẹ Íjíbítì nípasẹ̀ gbogbo nǹkan àgbàyanu tí màá ṣe níbẹ̀, lẹ́yìn náà, á jẹ́ kí ẹ lọ.+

  • Sáàmù 105:26, 27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Ó rán Mósè ìránṣẹ́ rẹ̀+

      Àti Áárónì,+ ẹni tí ó yàn.

      27 Wọ́n ṣe àwọn iṣẹ́ àmì rẹ̀ láàárín wọn,

      Àwọn iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ ní ilẹ̀ Hámù.+

  • Ìṣe 7:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Ọkùnrin yìí mú wọn jáde,+ ó ṣe àwọn ohun ìyanu* àti iṣẹ́ àmì ní Íjíbítì+ àti ní Òkun Pupa+ àti ní aginjù fún ogójì (40) ọdún.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́