Ẹ́kísódù 7:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ní tèmi, màá jẹ́ kí ọkàn Fáráò le,+ màá sì ṣe iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu tó pọ̀ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Ẹ́kísódù 12:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Àwọn ará Íjíbítì wá ń rọ àwọn èèyàn náà pé kí wọ́n tètè kúrò ní ilẹ̀ náà.+ Wọ́n sọ pé, “Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, gbogbo wa la máa kú!”+ Diutarónómì 6:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ojú wa ni Jèhófà ṣe ń fi àwọn iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu tó lágbára tó sì ń ṣọṣẹ́ kọ lu Íjíbítì,+ Fáráò àti gbogbo agbo ilé rẹ̀.+
33 Àwọn ará Íjíbítì wá ń rọ àwọn èèyàn náà pé kí wọ́n tètè kúrò ní ilẹ̀ náà.+ Wọ́n sọ pé, “Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, gbogbo wa la máa kú!”+
22 Ojú wa ni Jèhófà ṣe ń fi àwọn iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu tó lágbára tó sì ń ṣọṣẹ́ kọ lu Íjíbítì,+ Fáráò àti gbogbo agbo ilé rẹ̀.+