Ẹ́kísódù 10:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Wọlé lọ bá Fáráò, torí mo ti jẹ́ kí ọkàn òun àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ le,+ kí n lè ṣe àwọn iṣẹ́ àmì mi níwájú rẹ̀,+
10 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Wọlé lọ bá Fáráò, torí mo ti jẹ́ kí ọkàn òun àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ le,+ kí n lè ṣe àwọn iṣẹ́ àmì mi níwájú rẹ̀,+