-
Ẹ́kísódù 9:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Nígbà tí Fáráò rí i pé òjò, yìnyín àti ààrá ti dáwọ́ dúró, ló bá tún ṣẹ̀, ó sì mú kí ọkàn rẹ̀ le,+ òun àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀.