-
Ẹ́kísódù 8:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Nígbà tí Fáráò rí i pé ìtura dé, ó tún mú ọkàn rẹ̀ le,+ kò sì fetí sí wọn bí Jèhófà ṣe sọ.
-
-
Ẹ́kísódù 9:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Àmọ́ Jèhófà jẹ́ kí ọkàn Fáráò le, kò sì fetí sí wọn, bí Jèhófà ṣe sọ fún Mósè.+
-