ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 7:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ọjọ́ tó bá mú ẹbọ ìdúpẹ́ ti ẹbọ ìrẹ́pọ̀ rẹ̀ wá ni kó jẹ ẹran rẹ̀. Kò gbọ́dọ̀ ṣẹ́ ìkankan nínú rẹ̀ kù di àárọ̀.+

  • Léfítíkù 22:29, 30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 “Tí ẹ bá rú ẹbọ ìdúpẹ́ sí Jèhófà,+ kí ẹ rú ẹbọ náà kí ẹ bàa lè rí ìtẹ́wọ́gbà. 30 Ọjọ́ yẹn ni kí ẹ jẹ ẹ́. Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣẹ́ ìkankan lára rẹ̀ kù di àárọ̀ ọjọ́ kejì.+ Èmi ni Jèhófà.

  • Diutarónómì 16:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Kò gbọ́dọ̀ sí àpòrọ́ kíkan lọ́wọ́ rẹ ní gbogbo ilẹ̀ rẹ fún ọjọ́ méje,+ bẹ́ẹ̀ ni ìkankan nínú ẹran tí o bá fi rúbọ ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ àkọ́kọ́ ò gbọ́dọ̀ ṣẹ́ kù di ọjọ́ kejì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́