ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 20:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 “‘Tí ẹnì kan bá wà tó ń ṣépè* fún bàbá tàbí ìyá rẹ̀, ẹ gbọ́dọ̀ pa á.+ Ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ wà lórí òun fúnra rẹ̀, torí ó ti ṣépè fún bàbá tàbí ìyá rẹ̀.

  • Òwe 20:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ẹni tó bá bú bàbá àti ìyá rẹ̀,

      Fìtílà rẹ̀ yóò kú nígbà tí òkùnkùn bá ṣú.+

  • Òwe 30:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ìran kan wà tó ń gégùn-ún fún bàbá rẹ̀,

      Kì í sì í súre fún ìyá rẹ̀.+

  • Òwe 30:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ojú tó ń fi bàbá ṣẹ̀sín, tí kì í sì í ṣègbọràn sí ìyá,+

      Àwọn ẹyẹ ìwò tó wà ní àfonífojì yóò yọ ọ́ jáde,

      Àwọn ọmọ ẹyẹ idì yóò sì mú un jẹ.+

  • Mátíù 15:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Bí àpẹẹrẹ, Ọlọ́run sọ pé, ‘Bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ’+ àti pé, ‘Kí ẹ pa ẹni tó bá sọ̀rọ̀ òdì sí* bàbá tàbí ìyá rẹ̀.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́