-
Diutarónómì 21:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Kí gbogbo ọkùnrin ìlú rẹ̀ sọ ọ́ ní òkúta pa. Kí o mú ohun tó burú kúrò láàárín rẹ, tí gbogbo Ísírẹ́lì bá sì gbọ́, ẹ̀rù á bà wọ́n.+
-
-
Òwe 20:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ẹni tó bá bú bàbá àti ìyá rẹ̀,
Fìtílà rẹ̀ yóò kú nígbà tí òkùnkùn bá ṣú.+
-