Léfítíkù 24:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Kí ẹ kán eegun ẹni tó bá kán eegun ẹlòmíì, ojú dípò ojú, eyín dípò eyín, ohun tó bá ṣe fún ẹlòmíì ni kí ẹ ṣe fún òun náà.+ Mátíù 5:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 “Ẹ gbọ́ pé a sọ pé: ‘Ojú dípò ojú àti eyín dípò eyín.’+
20 Kí ẹ kán eegun ẹni tó bá kán eegun ẹlòmíì, ojú dípò ojú, eyín dípò eyín, ohun tó bá ṣe fún ẹlòmíì ni kí ẹ ṣe fún òun náà.+