Ẹ́kísódù 21:24, 25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 ojú dípò ojú, eyín dípò eyín, ọwọ́ dípò ọwọ́, ẹsẹ̀ dípò ẹsẹ̀,+ 25 kí o fi nǹkan jó ẹni tó bá fi nǹkan jó ẹnì kejì, ọgbẹ́ dípò ọgbẹ́, ẹ̀ṣẹ́ dípò ẹ̀ṣẹ́. Léfítíkù 24:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Kí ẹ kán eegun ẹni tó bá kán eegun ẹlòmíì, ojú dípò ojú, eyín dípò eyín, ohun tó bá ṣe fún ẹlòmíì ni kí ẹ ṣe fún òun náà.+ Diutarónómì 19:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 O* ò gbọ́dọ̀ káàánú rẹ̀:+ Kí o gba ẹ̀mí* dípò ẹ̀mí,* ojú dípò ojú, eyín dípò eyín, ọwọ́ dípò ọwọ́, ẹsẹ̀ dípò ẹsẹ̀.+
24 ojú dípò ojú, eyín dípò eyín, ọwọ́ dípò ọwọ́, ẹsẹ̀ dípò ẹsẹ̀,+ 25 kí o fi nǹkan jó ẹni tó bá fi nǹkan jó ẹnì kejì, ọgbẹ́ dípò ọgbẹ́, ẹ̀ṣẹ́ dípò ẹ̀ṣẹ́.
20 Kí ẹ kán eegun ẹni tó bá kán eegun ẹlòmíì, ojú dípò ojú, eyín dípò eyín, ohun tó bá ṣe fún ẹlòmíì ni kí ẹ ṣe fún òun náà.+
21 O* ò gbọ́dọ̀ káàánú rẹ̀:+ Kí o gba ẹ̀mí* dípò ẹ̀mí,* ojú dípò ojú, eyín dípò eyín, ọwọ́ dípò ọwọ́, ẹsẹ̀ dípò ẹsẹ̀.+