Diutarónómì 19:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 O* ò gbọ́dọ̀ káàánú rẹ̀:+ Kí o gba ẹ̀mí* dípò ẹ̀mí,* ojú dípò ojú, eyín dípò eyín, ọwọ́ dípò ọwọ́, ẹsẹ̀ dípò ẹsẹ̀.+ Mátíù 5:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 “Ẹ gbọ́ pé a sọ pé: ‘Ojú dípò ojú àti eyín dípò eyín.’+
21 O* ò gbọ́dọ̀ káàánú rẹ̀:+ Kí o gba ẹ̀mí* dípò ẹ̀mí,* ojú dípò ojú, eyín dípò eyín, ọwọ́ dípò ọwọ́, ẹsẹ̀ dípò ẹsẹ̀.+