-
Diutarónómì 22:28, 29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 “Tí ọkùnrin kan bá rí ọmọbìnrin kan tí kò tíì ní ìbálòpọ̀ rí, tí kò sì ní àfẹ́sọ́nà, tí ọkùnrin náà wá gbá a mú tó sì bá a sùn, tí ọ̀rọ̀ náà wá hàn síta,+ 29 kí ọkùnrin tó bá a sùn fún bàbá ọmọbìnrin náà ní àádọ́ta (50) ṣékélì fàdákà, obìnrin náà á sì di ìyàwó rẹ̀.+ Torí pé ọkùnrin náà ti dójú tì í, kò gbọ́dọ̀ kọ obìnrin náà sílẹ̀ ní gbogbo ọjọ́ tó bá fi wà láàyè.
-