Ẹ́kísódù 22:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “Ẹ ò gbọ́dọ̀ fìyà jẹ àjèjì tàbí kí ẹ ni ín lára,+ torí àjèjì lẹ jẹ́ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Ẹ́kísódù 23:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “O ò gbọ́dọ̀ ni àjèjì lára. Ẹ mọ bó ṣe máa ń rí kéèyàn jẹ́ àjèjì,* torí àjèjì lẹ jẹ́ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Léfítíkù 19:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Kí ẹ máa ṣe àjèjì tó ń bá yín gbé bí ọmọ ìbílẹ̀;+ kí ẹ nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ bí ara yín, torí àjèjì lẹ jẹ́ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín. Diutarónómì 10:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo fún ọmọ aláìníbaba* àti opó,+ ó sì nífẹ̀ẹ́ àjèjì,+ ó ń fún un ní oúnjẹ àti aṣọ.
9 “O ò gbọ́dọ̀ ni àjèjì lára. Ẹ mọ bó ṣe máa ń rí kéèyàn jẹ́ àjèjì,* torí àjèjì lẹ jẹ́ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+
34 Kí ẹ máa ṣe àjèjì tó ń bá yín gbé bí ọmọ ìbílẹ̀;+ kí ẹ nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ bí ara yín, torí àjèjì lẹ jẹ́ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.
18 Ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo fún ọmọ aláìníbaba* àti opó,+ ó sì nífẹ̀ẹ́ àjèjì,+ ó ń fún un ní oúnjẹ àti aṣọ.