Diutarónómì 10:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo fún ọmọ aláìníbaba* àti opó,+ ó sì nífẹ̀ẹ́ àjèjì,+ ó ń fún un ní oúnjẹ àti aṣọ. Sáàmù 34:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Aláìní yìí pe Jèhófà, ó sì gbọ́. Ó gbà á nínú gbogbo wàhálà rẹ̀.+
18 Ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo fún ọmọ aláìníbaba* àti opó,+ ó sì nífẹ̀ẹ́ àjèjì,+ ó ń fún un ní oúnjẹ àti aṣọ.