Diutarónómì 7:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ìwọ lo máa gba ìbùkún jù nínú gbogbo èèyàn;+ kò ní sí ọkùnrin tàbí obìnrin kankan láàárín rẹ tí kò ní bímọ, ẹran ọ̀sìn rẹ ò sì ní wà láìbímọ.+ Diutarónómì 28:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Ìbùkún ni fún àwọn ọmọ*+ rẹ àti èso ilẹ̀ rẹ àtàwọn ọmọ ẹran ọ̀sìn rẹ, ọmọ màlúù àti àgùntàn+ rẹ.
14 Ìwọ lo máa gba ìbùkún jù nínú gbogbo èèyàn;+ kò ní sí ọkùnrin tàbí obìnrin kankan láàárín rẹ tí kò ní bímọ, ẹran ọ̀sìn rẹ ò sì ní wà láìbímọ.+