Ẹ́kísódù 37:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Bẹ́sálẹ́lì+ wá fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe Àpótí.+ Gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́* méjì ààbọ̀, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀.+
37 Bẹ́sálẹ́lì+ wá fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe Àpótí.+ Gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́* méjì ààbọ̀, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀.+