Ẹ́kísódù 24:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Mósè wá wọ inú ìkùukùu náà, ó sì lọ sórí òkè náà.+ Mósè sì dúró lórí òkè náà fún ogójì (40) ọ̀sán àti ogójì (40) òru.+ Diutarónómì 9:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nígbà tí mo lọ sórí òkè láti gba àwọn wàláà òkúta,+ àwọn wàláà májẹ̀mú tí Jèhófà bá yín dá,+ ogójì (40) ọ̀sán àti ogójì (40) òru+ ni mo fi wà lórí òkè náà, tí mi ò jẹ, tí mi ò sì mu.
18 Mósè wá wọ inú ìkùukùu náà, ó sì lọ sórí òkè náà.+ Mósè sì dúró lórí òkè náà fún ogójì (40) ọ̀sán àti ogójì (40) òru.+
9 Nígbà tí mo lọ sórí òkè láti gba àwọn wàláà òkúta,+ àwọn wàláà májẹ̀mú tí Jèhófà bá yín dá,+ ogójì (40) ọ̀sán àti ogójì (40) òru+ ni mo fi wà lórí òkè náà, tí mi ò jẹ, tí mi ò sì mu.