-
Ìṣe 7:40Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
40 wọ́n sọ fún Áárónì pé: ‘Ṣe àwọn ọlọ́run fún wa tó máa ṣáájú wa. Torí a ò mọ ohun tó ti ṣẹlẹ̀ sí Mósè yìí, ẹni tó kó wa kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.’+
-