-
Ẹ́kísódù 32:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Wọ́n sọ fún mi pé, ‘Ṣe ọlọ́run kan fún wa tó máa ṣáájú wa, torí a ò mọ ohun tó ti ṣẹlẹ̀ sí Mósè yìí, ẹni tó kó wa kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.’+
-