ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 31:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Bákan náà, mo ti yan Òhólíábù  + ọmọ Áhísámákì látinú ẹ̀yà Dánì kó lè ràn án lọ́wọ́, màá sì fi ọgbọ́n sínú ọkàn gbogbo àwọn tó mọṣẹ́,* kí wọ́n lè ṣe gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún ọ:+

  • Ẹ́kísódù 31:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 àwọn aṣọ tí wọ́n hun dáadáa, aṣọ mímọ́ ti àlùfáà Áárónì, aṣọ tí àwọn ọmọ rẹ̀ máa fi ṣiṣẹ́ àlùfáà,+

  • Ẹ́kísódù 39:33
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Lẹ́yìn náà, wọ́n gbé àgọ́ ìjọsìn+ náà wá sọ́dọ̀ Mósè, àgọ́ náà+ àti gbogbo ohun èlò rẹ̀: àwọn ìkọ́ rẹ̀,+ àwọn férémù rẹ̀,+ àwọn ọ̀pá gbọọrọ rẹ̀+ àti àwọn òpó rẹ̀ àti àwọn ìtẹ́lẹ̀ oníhò rẹ̀;+

  • Ẹ́kísódù 39:41
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 41 àwọn aṣọ tí wọ́n hun dáadáa láti máa fi ṣiṣẹ́ ní ibi mímọ́, aṣọ mímọ́ ti àlùfáà Áárónì+ àti àwọn aṣọ tí àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ máa fi ṣiṣẹ́ àlùfáà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́