-
Ẹ́kísódù 28:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Kí o ṣe aṣọ mímọ́ fún Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ, kó lè ní ògo àti ẹwà.+
-
-
Ẹ́kísódù 39:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa ṣe aṣọ fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, ẹni tó ń hun aṣọ ló ṣe é,+
-