ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 2:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Kí ohunkóhun tó bá ṣẹ́ kù lára ọrẹ ọkà náà jẹ́ ti Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀,+ ohun mímọ́ jù lọ ló jẹ́+ látinú àwọn ọrẹ àfinásun sí Jèhófà.

  • Léfítíkù 5:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Kí àlùfáà ṣe ètùtù fún un torí ẹ̀ṣẹ̀ tó dá, èyí tó wù kó jẹ́ nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yìí, yóò sì rí ìdáríjì.+ Èyí tó ṣẹ́ kù nínú ọrẹ náà yóò di ti àlùfáà,+ bíi ti ọrẹ ọkà.’”+

  • Ìsíkíẹ́lì 44:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Àwọn ni yóò máa jẹ ọrẹ ọkà,+ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ àti ẹbọ ẹ̀bi,+ gbogbo ohun tí wọ́n bá sì yà sọ́tọ̀ ní Ísírẹ́lì yóò di tiwọn.+

  • 1 Kọ́ríńtì 9:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ṣé ẹ ò mọ̀ pé àwọn ọkùnrin tó ń ṣe iṣẹ́ mímọ́ máa ń jẹ àwọn nǹkan tẹ́ńpìlì àti pé àwọn tó ń ṣiṣẹ́ nídìí pẹpẹ máa ń gba ìpín nídìí pẹpẹ?+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́