-
Léfítíkù 6:17, 18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Wọn ò gbọ́dọ̀ fi ohunkóhun tó ní ìwúkàrà+ sí i. Mo ti fi ṣe ìpín tiwọn látinú àwọn ọrẹ àfinásun+ mi. Ohun mímọ́ jù lọ+ ni, bí ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ àti ẹbọ ẹ̀bi. 18 Gbogbo ọkùnrin nínú àwọn ọmọ Áárónì ni yóò jẹ+ ẹ́. Yóò jẹ́ ìpín wọn títí lọ látinú àwọn ọrẹ àfinásun+ sí Jèhófà, jálẹ̀ àwọn ìran wọn. Gbogbo ohun tó bá fara kàn wọ́n* yóò di mímọ́.’”
-
-
Léfítíkù 7:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 “‘Òfin ẹbọ ẹ̀bi+ nìyí: Ohun mímọ́ jù lọ ni.
-
-
1 Kọ́ríńtì 9:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ṣé ẹ ò mọ̀ pé àwọn ọkùnrin tó ń ṣe iṣẹ́ mímọ́ máa ń jẹ àwọn nǹkan tẹ́ńpìlì àti pé àwọn tó ń ṣiṣẹ́ nídìí pẹpẹ máa ń gba ìpín nídìí pẹpẹ?+
-