ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 6:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 “‘Òfin ọrẹ ọkà+ nìyí: Kí ẹ̀yin ọmọ Áárónì mú un wá síwájú Jèhófà, ní iwájú pẹpẹ.

  • Léfítíkù 6:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Gbogbo ọkùnrin nínú àwọn ọmọ Áárónì ni yóò jẹ+ ẹ́. Yóò jẹ́ ìpín wọn títí lọ látinú àwọn ọrẹ àfinásun+ sí Jèhófà, jálẹ̀ àwọn ìran wọn. Gbogbo ohun tó bá fara kàn wọ́n* yóò di mímọ́.’”

  • Léfítíkù 21:21, 22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Ọkùnrin èyíkéyìí tó ní àbùkù lára nínú àwọn ọmọ* àlùfáà Áárónì ò gbọ́dọ̀ sún mọ́ tòsí láti gbé àwọn ọrẹ àfinásun sí Jèhófà wá. Kò gbọ́dọ̀ sún mọ́ tòsí láti gbé oúnjẹ Ọlọ́run rẹ̀ wá torí ó ní àbùkù lára. 22 Ó lè jẹ oúnjẹ Ọlọ́run rẹ̀, látinú àwọn ohun mímọ́ jù lọ+ àti àwọn ohun mímọ́.+

  • Nọ́ńbà 18:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Inú ibi mímọ́ jù lọ ni kí o ti jẹ ẹ́.+ Gbogbo ọkùnrin ló lè jẹ ẹ́. Kó jẹ́ ohun mímọ́ fún ọ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́