ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 20:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 “‘Kí ẹ ya ara yín sí mímọ́, kí ẹ sì di mímọ́,+ torí èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.

  • Léfítíkù 20:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Kí ẹ jẹ́ mímọ́ fún mi, torí èmi Jèhófà jẹ́ mímọ́,+ mo sì ń yà yín sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn èèyàn yòókù kí ẹ lè di tèmi.+

  • Jóṣúà 24:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Jóṣúà wá sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ ò lè sin Jèhófà, torí pé Ọlọ́run mímọ́ ni;+ Ọlọ́run tó fẹ́ kí a máa jọ́sìn òun nìkan ṣoṣo ni.+ Kò ní dárí àwọn ìṣìnà* àtàwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín jì yín.+

  • 1 Sámúẹ́lì 2:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Kò sí ẹni tí ó mọ́ bíi Jèhófà,

      Kò sí ẹlòmíràn, àfi ìwọ,+

      Kò sì sí àpáta tí ó dà bí Ọlọ́run wa.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́