ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 23:20, 21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 “Màá rán áńgẹ́lì kan ṣáájú yín+ kó lè dáàbò bò yín lójú ọ̀nà, kó sì mú yín wá síbi tí mo ti ṣètò sílẹ̀.+ 21 Kí ẹ fetí sí i, kí ẹ sì ṣègbọràn sí ohùn rẹ̀. Ẹ má ṣọ̀tẹ̀ sí i, torí kò ní dárí ẹ̀ṣẹ̀ yín jì,+ torí pé orúkọ mi wà lára rẹ̀.

  • Nọ́ńbà 14:35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 35 “‘“Èmi Jèhófà ti sọ̀rọ̀. Ohun tí màá ṣe fún àwọn èèyàn burúkú yìí tí wọ́n kóra jọ láti ta kò mí nìyí: Inú aginjù yìí ni wọ́n máa ṣègbé sí, ibí ni wọ́n sì máa kú sí.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́