Jóṣúà 7:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ísírẹ́lì ti ṣẹ̀. Wọ́n ti da májẹ̀mú mi+ tí mo pa láṣẹ pé kí wọ́n pa mọ́. Wọ́n kó lára ohun tí wọ́n máa pa run,+ wọ́n jí i,+ wọ́n sì lọ kó o pa mọ́ sáàárín ohun ìní wọn.+
11 Ísírẹ́lì ti ṣẹ̀. Wọ́n ti da májẹ̀mú mi+ tí mo pa láṣẹ pé kí wọ́n pa mọ́. Wọ́n kó lára ohun tí wọ́n máa pa run,+ wọ́n jí i,+ wọ́n sì lọ kó o pa mọ́ sáàárín ohun ìní wọn.+