Léfítíkù 16:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ọjọ́ yìí ni wọ́n á ṣe ètùtù+ fún yín láti kéde pé ẹ jẹ́ mímọ́. Ẹ máa di mímọ́ kúrò nínú gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ yín níwájú Jèhófà.+ Léfítíkù 23:27, 28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “Ọjọ́ kẹwàá oṣù keje yìí ni Ọjọ́ Ètùtù.+ Kí ẹ ṣe àpéjọ mímọ́, kí ẹ pọ́n ara yín* lójú,+ kí ẹ sì ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà. 28 Ẹ má ṣe iṣẹ́ kankan ní ọjọ́ yìí gangan, torí ó jẹ́ ọjọ́ ètùtù tí wọ́n á ṣe ètùtù+ fún yín níwájú Jèhófà Ọlọ́run yín.
30 Ọjọ́ yìí ni wọ́n á ṣe ètùtù+ fún yín láti kéde pé ẹ jẹ́ mímọ́. Ẹ máa di mímọ́ kúrò nínú gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ yín níwájú Jèhófà.+
27 “Ọjọ́ kẹwàá oṣù keje yìí ni Ọjọ́ Ètùtù.+ Kí ẹ ṣe àpéjọ mímọ́, kí ẹ pọ́n ara yín* lójú,+ kí ẹ sì ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà. 28 Ẹ má ṣe iṣẹ́ kankan ní ọjọ́ yìí gangan, torí ó jẹ́ ọjọ́ ètùtù tí wọ́n á ṣe ètùtù+ fún yín níwájú Jèhófà Ọlọ́run yín.