- 
	                        
            
            Léfítíkù 26:3-5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        3 “‘Tí ẹ bá ń tẹ̀ lé àwọn òfin mi, tí ẹ̀ ń pa àwọn àṣẹ mi mọ́, tí ẹ sì ń ṣe wọ́n,+ 4 èmi yóò rọ ọ̀wààrà òjò fún yín ní àkókò tó yẹ,+ ilẹ̀ yóò mú èso jáde,+ àwọn igi oko yóò sì so èso. 5 Ẹ ó máa pakà títí di ìgbà tí ẹ máa kórè èso àjàrà, ẹ ó sì máa kórè èso àjàrà títí di ìgbà tí ẹ máa fúnrúgbìn; ẹ ó jẹun ní àjẹyó, ẹ ó sì máa gbé láìséwu ní ilẹ̀ yín.+ 
 
-