-
Nọ́ńbà 35:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Kí ibi ìjẹko tó yí àwọn ìlú tí ẹ máa fún àwọn ọmọ Léfì ká jẹ́ ẹgbẹ̀rún (1,000) ìgbọ̀nwọ́* láti ògiri ìlú náà yí ká.
-
-
Diutarónómì 18:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 “Wọn ò ní fún àwọn àlùfáà tí wọ́n jẹ́ ọmọ Léfì àti gbogbo ẹ̀yà Léfì pátá ní ìpín tàbí ogún kankan ní Ísírẹ́lì. Wọ́n á máa jẹ lára àwọn ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, èyí tó jẹ́ tirẹ̀.+
-