-
Jóṣúà 5:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ti fi ogójì (40) ọdún+ rìn ní aginjù, títí gbogbo orílẹ̀-èdè náà fi kú, ìyẹn àwọn ọkùnrin ogun tó kúrò ní Íjíbítì, tí wọn ò fetí sí ohùn Jèhófà.+ Jèhófà búra fún wọn pé òun kò ní jẹ́ kí wọ́n rí ilẹ̀+ tí Jèhófà búra fún àwọn baba ńlá wọn pé òun máa fún wa,+ ilẹ̀ tí wàrà àti oyin ti ń ṣàn.+
-
-
Sáàmù 95:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ogójì (40) ọdún ni mo fi kórìíra ìran yẹn, mo sì sọ pé:
“Àwọn èèyàn tó máa ń ṣìnà nínú ọkàn wọn ni wọ́n;
Wọn ò tíì mọ àwọn ọ̀nà mi.”
-
-
Ìṣe 13:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Nǹkan bí ogójì (40) ọdún ló fi fara dà á fún wọn ní aginjù.+
-