ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 21:12, 13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 “Tí ẹnì kan bá lu èèyàn pa, kí ẹ pa onítọ̀hún.+ 13 Àmọ́ tó bá jẹ́ pé kò mọ̀ọ́mọ̀ pa á, tí Ọlọ́run tòótọ́ sì fàyè gbà á, màá yan ibì kan fún ọ tó lè sá lọ.+

  • Diutarónómì 4:42
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 42 Tí apààyàn èyíkéyìí bá ṣèèṣì pa ọmọnìkejì rẹ̀, tí kì í sì í ṣe pé ó kórìíra rẹ̀ tẹ́lẹ̀,+ kó sá lọ sí ọ̀kan lára àwọn ìlú yìí, kí wọ́n má bàa pa á.+

  • Diutarónómì 19:4, 5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 “Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí apààyàn tó bá sá lọ síbẹ̀ kó má bàa kú nìyí: Tó bá ṣèèṣì pa ẹnì kejì rẹ̀, tí kò sì kórìíra rẹ̀ tẹ́lẹ̀;+ 5 bóyá òun àti ẹnì kejì rẹ̀ jọ lọ ṣa igi nínú igbó, tó wá gbé àáké sókè láti gé igi, àmọ́ tí irin àáké náà fò yọ, tó ba ẹnì kejì rẹ̀, tó sì kú, kí apààyàn náà sá lọ sí ọ̀kan lára àwọn ìlú yìí, kó má bàa kú.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́